Intro:
Dakoto si mofe dakolo si
Ti n ba shey tan mo ma shankolo si
Chorus:
Idi Rabata! Aunty Alaba! To da bi Alapa! Ma fi jo galala (X2)
Shey ki n la? Shey ki n la? Shey ki n la? LALAKUKULALA (X2)
Verse 1(Oladips):
Kofun won lotun losi
A shaa mo pe awon eleyii o n shey oloshii
Sango nie jhoor e m fun lowkey
Mo ma kan eh leyin o ma land ni igbobi
O ti pe ti mo fe le eh nibe
Mo fe ponke mo fe gehgehtigeh
Nkan to shey titi tese fi keh
Omo to je pe ko sebe tile
Useless Bottom! Shaking By Force!
Emi lokan gan! Its not my fault
Mo fe dakoto si mo fe dakolo si
Ti n ba shey tan ma fi shankolo si
Mo fe ma debe laaro kutu
Ah!! Oya pamukutu!
Chorus:
Idi Rabata! Aunty Alaba! To da bi Alapa! Ma fi jo galala (X2)
Shey ki n la? Shey ki n la? Shey ki n la? LALAKUKULALA (X2)
Verse 2(Reminisce):
Ibile leso leso lo mo n basa
Ti plug o ba wole lo converter
Engine mhii muna wa bi ti t’inverter
Oya kana mhii da kalo montana
Lalakukulala
Je ki n pasapusupasa
Oda omo oni bukata
Yeba! Ko tun wa wo pata
Idiaraba lomo correcti
Tan WiFi eh ki n connecti
Iwo omo yii over collecti
Ki n gba ile fun eh room toleti
Ohhh! Ahhh! Kama yata yo yahh !
Yeehhhpaaa! O de m’ogiri ko da
Chorus:
Idi Rabata! Aunty Alaba! To da bi Alapa! Ma fi jo galala (X2)
Shey ki n la? Shey ki n la? Shey ki n la? LALAKUKULALA (X2)